Owe 28:27 - Compare All Versions
Owe 28:27 YBCV (Bibeli Mimọ)
Ẹniti o ba nfi fun olupọnju kì yio ṣe alaini: ṣugbọn ẹniti o mu oju rẹ̀ kuro, yio gbà egún pupọ.
Pín
Owe 28 YBCVOwe 28:27 YCE (Yoruba Bible)
Ẹni tí ó ta talaka lọ́rẹ kò ní ṣe aláìní, ṣugbọn ẹni tí ó fojú pamọ́ fún wọn, yóo gba ègún.
Pín
Owe 28 YCEOwe 28:27 BMYO (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ẹni tí ó ń fi fún tálákà kì yóò ṣe aláìní ohunkóhun, ṣùgbọ́n ẹni tí ó di ojú rẹ̀ sí wọn gba ọ̀pọ̀lọpọ̀ ègún.
Pín
Owe 28 BMYO