Owe 30:5 - Compare All Versions

Owe 30:5 YBCV (Bibeli Mimọ)

Gbogbo ọ̀rọ Oluwa jẹ́ otitọ: on li asà fun gbogbo awọn ti o gbẹkẹ wọn le e.

Owe 30:5 YCE (Yoruba Bible)

Kò sí ọ̀rọ̀ Ọlọrun kankan tí ó ń yẹ̀, òun ni ààbò fún àwọn tí wọ́n wá ààbò lọ sọ́dọ̀ rẹ̀.

Owe 30:5 BMYO (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)

“Gbogbo ọ̀rọ̀ Ọlọ́run jẹ́ aláìlábùkù; òun ni ààbò fún gbogbo ẹni fi í ṣe ibi ìpamọ́ wọn.