Owe 31:30
Owe 31:30 Bibeli Mimọ (YBCV)
Oju daradara li ẹ̀tan, ẹwà si jasi asan: ṣugbọn obinrin ti o bẹ̀ru Oluwa, on ni ki a fi iyìn fun.
Pín
Kà Owe 31Owe 31:30 Yoruba Bible (YCE)
Ẹ̀tàn ni ojú dáradára, asán sì ni ẹwà, obinrin tí ó bá bẹ̀rù OLUWA ni ó yẹ kí á yìn.
Pín
Kà Owe 31