Owe 4:7
Owe 4:7 Bibeli Mimọ (YBCV)
Ipilẹṣẹ ọgbọ́n ni lati ni ọgbọ́n: ati pẹlu ini rẹ gbogbo, ni oye.
Pín
Kà Owe 4Owe 4:7 Yoruba Bible (YCE)
Bí o bá fẹ́ gbọ́n, bẹ̀rẹ̀ sí kọ́gbọ́n, ohun yòówù tí o lè tún ní, ọgbọ́n ló jù, nítorí náà jẹ́ ọlọ́gbọ́n.
Pín
Kà Owe 4