O. Daf 119:2
O. Daf 119:2 Bibeli Mimọ (YBCV)
Ibukún ni fun awọn ti npa ẹri rẹ̀ mọ́, ti si nwá a kiri tinu-tinu gbogbo.
O. Daf 119:2 Yoruba Bible (YCE)
Ayọ̀ ń bẹ fún àwọn tí ń pa òfin rẹ̀ mọ́, tí wọn ń fi tọkàntọkàn ṣe ìfẹ́ rẹ̀.