Ṣe àfiwé gbogbo èyà
O. Daf 125:1YBCV(Bibeli Mimọ)
AWỌN ti o gbẹkẹle Oluwa yio dabi òke Sioni, ti a kò le ṣi ni idi, bikoṣepe o duro lailai.
O. Daf 125:1BMYO(Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Àwọn tí ó gbẹ́kẹ̀lé OLúWA yóò dàbí òkè Sioni, tí a kò lè ṣí ní ìdí, bí kò ṣe pé ó dúró láéláé.
O. Daf 125:1YCE(Yoruba Bible)
Àwọn tí ó gbẹ́kẹ̀lé OLUWA dàbí òkè Sioni, tí ẹnikẹ́ni kò lè ṣí nídìí, ṣugbọn tí ó wà títí lae.