Àmì Ìdánimọ̀ Ohun-èlò Bíbélì
Ṣe Àwárí

Ṣe àfiwé gbogbo èyà

O. Daf 125:2YBCV(Bibeli Mimọ)

Bi òke nla ti yi Jerusalemu ka, bẹ̃li Oluwa yi awọn enia rẹ̀ ka lati isisiyi lọ ati titi lailai.

O. Daf 125:2BMYO(Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)

Bí òkè ńlá ti yí Jerusalẹmu ká, bẹ́ẹ̀ ni OLúWA yí ènìyàn ká láti ìsinsin yìí lọ àti títí láéláé.

O. Daf 125:2YCE(Yoruba Bible)

Bí òkè ńlá ti yí Jerusalẹmu ká, bẹ́ẹ̀ ni OLUWA yí àwọn eniyan rẹ̀ ká, láti ìsinsìnyìí lọ ati títí lae.