Àmì Ìdánimọ̀ Ohun-èlò Bíbélì
Ṣe Àwárí

Ṣe àfiwé gbogbo èyà

O. Daf 126:3YBCV(Bibeli Mimọ)

Oluwa ṣe ohun nla fun wa: nitorina awa nyọ̀.

O. Daf 126:3BMYO(Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)

OLúWA ṣe ohun ńlá fún wa; nítorí náà àwa ń yọ̀.

O. Daf 126:3YCE(Yoruba Bible)

Lóòótọ́, OLUWA ṣe nǹkan ńlá fún wa, nítorí náà à ń yọ̀ ṣẹ̀ṣẹ̀.