Ṣe àfiwé gbogbo èyà
O. Daf 126:5BMYO(Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Àwọn tí ń fi omijé fún irúgbìn yóò fi ayọ̀ ka.
O. Daf 126:5YCE(Yoruba Bible)
Àwọn tí ń fọ́n irúgbìn pẹlu omi lójú, jẹ́ kí wọn kórè rẹ̀ tayọ̀tayọ̀.