Àmì Ìdánimọ̀ Ohun-èlò Bíbélì
Ṣe Àwárí

Ṣe àfiwé gbogbo èyà

O. Daf 127:1YBCV(Bibeli Mimọ)

BIKOṢEPE Oluwa ba kọ́ ile na, awọn ti nkọ́ ọ nṣiṣẹ lasan: bikoṣepe Oluwa ba pa ilu mọ́, oluṣọ ji lasan.

O. Daf 127:1BMYO(Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)

Bí kò ṣe pé OLúWA bá kọ́ ilé náà àwọn tí ń kọ́ ọ ń ṣiṣẹ́ lásán ni; bí kò ṣe pé OLúWA bá pa ìlú mọ́, olùṣọ́ jí lásán.

O. Daf 127:1YCE(Yoruba Bible)

Bí OLUWA kò bá kọ́ ilé, asán ni wahala àwọn tí ń kọ́ ọ. Bí OLUWA kò bá ṣọ́ ìlú, asán ni àìsùn àwọn aṣọ́de.