Àmì Ìdánimọ̀ Ohun-èlò Bíbélì
Ṣe Àwárí

Ṣe àfiwé gbogbo èyà

O. Daf 127:3-4YBCV(Bibeli Mimọ)

Kiyesi i, awọn ọmọ ni ini Oluwa: ọmọ inu si li ère rẹ̀. Bi ọfà ti ri li ọwọ alagbara, bẹ̃li awọn ọmọ igbà èwe rẹ.

O. Daf 127:3-4BMYO(Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)

Kíyèsi i, àwọn ọmọ ni ìní OLúWA: ọmọ inú sì ni èrè rẹ̀. Bí ọfà ti rí ní ọwọ́ alágbára, bẹ́ẹ̀ ni àwọn ọmọ èwe.

O. Daf 127:3-4YCE(Yoruba Bible)

Wò ó! Ẹ̀bùn OLUWA ni ọmọ; òun ní fi oyún inú ṣìkẹ́ eniyan. Bí ọfà ti rí lọ́wọ́ jagunjagun, bẹ́ẹ̀ ni àwọn ọmọ ìgbà òwúrọ̀ ẹni.