Àmì Ìdánimọ̀ Ohun-èlò Bíbélì
Ṣe Àwárí

Ṣe àfiwé gbogbo èyà

O. Daf 130:1YBCV(Bibeli Mimọ)

LATI inu ibu wá li emi kepe ọ, Oluwa.

O. Daf 130:1BMYO(Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)

Láti inú ibú wá ni èmi ń ké pè é ọ́ OLúWA

O. Daf 130:1YCE(Yoruba Bible)

Ninu ìṣòro ńlá ni mò ń ké pè ọ́, OLUWA!