Àmì Ìdánimọ̀ Ohun-èlò Bíbélì
Ṣe Àwárí

Ṣe àfiwé gbogbo èyà

O. Daf 130:4YBCV(Bibeli Mimọ)

Nitori idariji wà lọdọ rẹ, ki a le ma bẹ̀ru rẹ.

O. Daf 130:4BMYO(Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)

Nítorí ìdáríjì wà lọ́dọ̀ rẹ, kí a lè máa bẹ̀rù rẹ.

O. Daf 130:4YCE(Yoruba Bible)

Ṣugbọn ní ìkáwọ́ rẹ ni ìdáríjì wà, kí á lè máa bẹ̀rù rẹ.