O. Daf 27:14
O. Daf 27:14 Bibeli Mimọ (YBCV)
Duro de Oluwa; ki o si tújuka, yio si mu ọ li aiya le: mo ni, duro de Oluwa.
Pín
Kà O. Daf 27O. Daf 27:14 Yoruba Bible (YCE)
Dúró de OLUWA, ṣe bí akin, kí o sì mú ọkàn gírí, àní, dúró de OLUWA.
Pín
Kà O. Daf 27