Ṣe àfiwé gbogbo èyà
O. Daf 34:10YBCV(Bibeli Mimọ)
Awọn ọmọ kiniun a ma ṣe alaini, ebi a si ma pa wọn: ṣugbọn awọn ti nwá Oluwa, kì yio ṣe alaini ohun ti o dara.
O. Daf 34:10BMYO(Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Àwọn ọmọ kìnnìún a máa ṣe aláìní ebi a sì máa pa wọ́n; ṣùgbọ́n àwọn tí ó wá OLúWA kì yóò ṣe aláìní ohun tí ó dára.
O. Daf 34:10YCE(Yoruba Bible)
Àwọn ọmọ kinniun a máa ṣe aláìní, ebi a sì máa pa wọ́n; ṣugbọn àwọn tí wọ́n bá ń wá OLUWA kò ní ṣe aláìní ohun rere kankan.
Pín
O. Daf 34YCE