O. Daf 4:8
O. Daf 4:8 Bibeli Mimọ (YBCV)
Emi o dubulẹ pẹlu li alafia, emi o si sùn; nitori iwọ, Oluwa, nikanṣoṣo li o nmu mi joko li ailewu.
Pín
Kà O. Daf 4O. Daf 4:8 Yoruba Bible (YCE)
N óo dùbúlẹ̀, n óo sì sùn ní alaafia, nítorí ìwọ OLUWA nìkan ni o mú mi wà láìléwu.
Pín
Kà O. Daf 4