Àmì Ìdánimọ̀ Ohun-èlò Bíbélì
Ṣe Àwárí

Ṣe àfiwé gbogbo èyà

O. Daf 49:15YBCV(Bibeli Mimọ)

Ṣugbọn Ọlọrun ni yio rà ọkàn mi lọwọ isa-okú: nitoripe on o gbà mi.

O. Daf 49:15BMYO(Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)

Ṣùgbọ́n Ọlọ́run yóò ra ọkàn mi padà kúrò nínú isà òkú, yóò gbé mi lọ sọ́dọ̀ òun fún rara rẹ̀.

O. Daf 49:15YCE(Yoruba Bible)

Ṣugbọn Ọlọrun yóo ra ẹ̀mí mi pada lọ́wọ́ ikú nítorí pé yóo gbà mí.