Ṣe àfiwé gbogbo èyà
O. Daf 49:20YBCV(Bibeli Mimọ)
Ọkunrin ti o wà ninu ọlá, ti kò moye, o dabi ẹranko ti o ṣegbe.
O. Daf 49:20BMYO(Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ọkùnrin tí ó ní ọlá tí kò ní òye dàbí ẹranko tí ó ṣègbé.
O. Daf 49:20YCE(Yoruba Bible)
Eniyan kò lè máa gbé inú ọlá rẹ̀ títí ayé; bí ẹranko tíí kú, ni òun náà óo ku.
Pín
O. Daf 49YCE