Ṣe àfiwé gbogbo èyà
O. Daf 54:7YBCV(Bibeli Mimọ)
Nitori o ti yọ mi kuro ninu iṣẹ́ gbogbo: oju mi si ri ifẹ rẹ̀ lara awọn ọta mi.
O. Daf 54:7BMYO(Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nítorí tí ó yọ mí kúrò nínú ibi gbogbo ojú mi ti wo ìṣẹ́gun lórí ọ̀tá mi.
O. Daf 54:7YCE(Yoruba Bible)
O ti yọ mí ninu gbogbo ìṣòro mi, mo sì ti fi ojú mi rí ìṣubú àwọn ọ̀tá mi.
Pín
O. Daf 54YCE