Ṣe àfiwé gbogbo èyà
O. Daf 55:1YBCV(Bibeli Mimọ)
FETI si adura mi, Ọlọrun; má si ṣe fi ara rẹ pamọ kuro ninu ẹ̀bẹ mi.
O. Daf 55:1BMYO(Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Fi etí sí àdúrà mi, Ọlọ́run, má ṣe fi ojú pa ẹ̀bẹ̀ mi rẹ́
O. Daf 55:1YCE(Yoruba Bible)
Tẹ́tí sí adura mi, Ọlọrun, má sì fara pamọ́ nígbà tí mo bá ń bẹ̀bẹ̀.
Pín
O. Daf 55YCE