Ṣe àfiwé gbogbo èyà
O. Daf 55:18YBCV(Bibeli Mimọ)
O ti gbà ọkàn mi silẹ li alafia lọwọ ogun ti o ti dó tì mi: nitoripe pẹlu ọ̀pọlọpọ enia ni nwọn dide si mi.
O. Daf 55:18BMYO(Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ó rà mí padà láìléwu kúrò nínú ogun tí ó dìde sí mi, nítorí ọ̀pọ̀lọpọ̀ ni ó dìde sí mi.
O. Daf 55:18YCE(Yoruba Bible)
Yóo yọ mí láìfarapa, ninu ogun tí mò ń jà, nítorí ọ̀pọ̀ ni àwọn tí wọ́n dojú kọ mí, tí wọn ń bá mi jà.
Pín
O. Daf 55YCE