Àmì Ìdánimọ̀ Ohun-èlò Bíbélì
Ṣe Àwárí

Ṣe àfiwé gbogbo èyà

O. Daf 60:11YBCV(Bibeli Mimọ)

Fun wa ni iranlọwọ ninu ipọnju: nitori pe asan ni iranlọwọ enia.

O. Daf 60:11BMYO(Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)

Fún wa ní ìrànlọ́wọ́ lórí àwọn ọ̀tá, nítorí asán ni ìrànlọ́wọ́ ènìyàn.

O. Daf 60:11YCE(Yoruba Bible)

Ràn wá lọ́wọ́, bá wa gbógun ti àwọn ọ̀tá wa, nítorí pé asán ni ìrànlọ́wọ́ eniyan.