Ṣe àfiwé gbogbo èyà
O. Daf 60:12YBCV(Bibeli Mimọ)
Nipasẹ Ọlọrun li awa o ṣe akin: nitori on ni yio tẹ̀ awọn ọta wa mọlẹ.
O. Daf 60:12BMYO(Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nípa Ọlọ́run ni a óò ní ìṣẹ́gun, yóò sì tẹ àwọn ọ̀tá wa mọ́lẹ̀.
O. Daf 60:12YCE(Yoruba Bible)
Pẹlu àtìlẹ́yìn Ọlọrun a óo ṣe akin, nítorí òun ni yóo tẹ àwọn ọ̀tá wa mọ́lẹ̀.
Pín
O. Daf 60YCE