Ṣe àfiwé gbogbo èyà
O. Daf 61:3YBCV(Bibeli Mimọ)
Nitori iwọ li o ti nṣe àbo fun mi, ati ile-iṣọ agbara lọwọ ọta nì.
O. Daf 61:3BMYO(Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nítorí ìwọ ti jẹ́ ibi ààbò mi, ilé ìṣọ́ agbára àwọn ọ̀tá.
O. Daf 61:3YCE(Yoruba Bible)
nítorí ìwọ ni ààbò mi, ìwọ ni ilé ìṣọ́ tí ó lágbára láti dáàbò bò mí lọ́wọ́ ọ̀tá.
Pín
O. Daf 61YCE