Ẹniti iṣe Ọlọrun wa li Ọlọrun igbala; ati lọwọ Jehofah Oluwa, li amúwa lọwọ ikú wà.
Ọlọrun tí ń gbani là ni Ọlọrun wa; OLUWA Ọlọrun ni ń yọni lọ́wọ́ ikú.
Ọlọ́run wa jẹ́ Ọlọ́run tó ń gbàlà àti sí OLúWA Olódùmarè ni ó ń gbà wá lọ́wọ́ ikú.
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò