Ifi 12:1-2
Ifi 12:1-2 Bibeli Mimọ (YBCV)
ÀMI nla kan si hàn li ọrun; obinrin kan ti a fi õrùn wọ̀ li aṣọ, oṣupa si mbẹ labẹ ẹsẹ rẹ̀, ade onirawọ mejila si mbẹ li ori rẹ̀: O si lóyun, o si kigbe ni irọbi, o si wà ni irora ati bimọ.
Pín
Kà Ifi 12