Rom 6:23
Rom 6:23 Bibeli Mimọ (YBCV)
Nitori ikú li ère ẹ̀ṣẹ; ṣugbọn ẹ̀bun ọfẹ Ọlọrun ni ìye ti kò nipẹkun, ninu Kristi Jesu Oluwa wa.
Pín
Kà Rom 6Rom 6:23 Yoruba Bible (YCE)
Ikú ni èrè ẹ̀ṣẹ̀, ṣugbọn ẹ̀bùn Ọlọrun ni ìyè ainipẹkun pẹlu Jesu Kristi Oluwa wa.
Pín
Kà Rom 6