Oluwa yio si jọba lori gbogbo aiye: li ọjọ na ni Oluwa kan yio wà, orukọ rẹ̀ yio si jẹ ọkan.
OLUWA yóo wá jọba ní gbogbo ayé; Ọlọrun nìkan ni gbogbo aráyé yóo máa sìn nígbà náà, orúkọ kanṣoṣo ni wọn yóo sì mọ̀ ọ́n.
OLúWA yóò sì jẹ ọba lórí gbogbo ayé; ni ọjọ́ náà ni OLúWA kan yóò wa orúkọ rẹ̀ nìkan náà ni orúkọ.
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò