Ìhìnrere Matiu
Ọjọ́ 28
Nínú ètò ẹsẹ̀-Bibeli-kan-lójúmọ́ yìí jàlẹ̀ Ìhìnrere ti Matiu, ìwọ yóò ṣalábapàdé Jesu Ọba: ìmúṣẹ àsọtẹ́lẹ̀ Májẹ̀mú Lailai, àti ìrètí gbogbo àgbáyé. Ṣàwárí bí o ṣe lè wọ Ìjọba Ọlọrun, mú Ìjọba Ọlọrun gbòòrò síi káàkiri àgbáyé, kí o sì ní ìrírí Ìjọba Ọlọrun, nípasẹ̀ àlàyé Matiu nípa àwọn ẹ̀kọ́, iṣẹ́ ìyanu, ikú, àti àjínde Jesu. YouVersion ni ó ṣàgbékalẹ̀ ètò yìí.
A yoo fẹ lati dupẹ lọwọ Mount Zion Faith Ministry fun ipese eto yii. Fun alaye diẹ sii, jọwọ ṣabẹwo: https://mountzionfilm.org/