Ohun Èlò Bíbélì jẹ ọfẹ pátápátá, laisi ìpolówó àti àwọn rírà ni-app. Gba ohun èlò
NÍPA ÌGBÀGBỌ́

Ọjọ́ 7
Ìgbàgbọ́ ni ìṣẹ́gun onígbàgbọ́. Nípasẹ̀ ìgbàgbọ́, a ń ṣẹ́gun ayé, a ń borí ìṣòro, a sì ń gba àbájáde rere. Bí a ba lóye ìgbàgbọ́ dáadáa tí a sì lo ó, a ó máa rìn nínú ìṣẹ́gun ní gbogbo ìgbà.
A yoo fẹ lati dupẹ lọwọ Olufemi Ezekiel Adebayo fun ipese eto yii. Fun alaye diẹ sii, jọwọ ṣabẹwo: www.femiadebayo.org




