1
ÌṢE ÀWỌN APOSTELI 4:12
Yoruba Bible
Kò sí ìgbàlà lọ́dọ̀ ẹlòmíràn; bẹ́ẹ̀ ni kò sí orúkọ mìíràn tí a fi fún eniyan lábẹ́ ọ̀run nípa èyí tí a lè fi gba eniyan là.”
موازنہ
تلاش ÌṢE ÀWỌN APOSTELI 4:12
2
ÌṢE ÀWỌN APOSTELI 4:31
Bí wọ́n ti ń gbadura, ibi tí wọ́n péjọ sí mì tìtì, gbogbo wọn bá kún fún Ẹ̀mí Mímọ́, wọ́n bá ń fi ìgboyà sọ ọ̀rọ̀ Ọlọrun.
تلاش ÌṢE ÀWỌN APOSTELI 4:31
3
ÌṢE ÀWỌN APOSTELI 4:29
Ǹjẹ́ nisinsinyii, Oluwa, ṣe akiyesi bí wọ́n ti ń halẹ̀, kí o sì fún àwọn iranṣẹ rẹ ní ìgboyà ní gbogbo ọ̀nà láti lè sọ ọ̀rọ̀ rẹ.
تلاش ÌṢE ÀWỌN APOSTELI 4:29
4
ÌṢE ÀWỌN APOSTELI 4:11
Jesu yìí ni ‘Òkúta tí àwọn ọ̀mọ̀lé kọ̀ sílẹ̀, tí ó wá di òkúta pataki igun-ilé.’
تلاش ÌṢE ÀWỌN APOSTELI 4:11
5
ÌṢE ÀWỌN APOSTELI 4:13
Nígbà tí wọ́n rí ìgboyà Peteru ati ti Johanu, tí wọ́n wòye pé wọn kò mọ ìwé àtipé òpè eniyan ni wọ́n, ẹnu yà wọ́n. Wọ́n ṣe akiyesi wọn pé wọ́n ti wà pẹlu Jesu.
تلاش ÌṢE ÀWỌN APOSTELI 4:13
6
ÌṢE ÀWỌN APOSTELI 4:32
Ọkàn kan ati ẹ̀mí kan ni gbogbo àwùjọ àwọn onigbagbọ ní. Kò sí ẹnìkan ninu wọn tí ó dá àwọn nǹkan tirẹ̀ yà sọ́tọ̀, wọ́n jọ ní gbogbo nǹkan papọ̀ ni.
تلاش ÌṢE ÀWỌN APOSTELI 4:32
صفحہ اول
بائبل
مطالعاتی منصوبہ
Videos