← Àwon ètò
Àwọn ètò kíkà ọ̀fé àti àyọkà tó ní ṣe pẹ̀lú Mat 18:35
ÌDÁRÍJÌN
3 Awọn ọjọ
Ìdáríjìn jẹ́ ọ̀kan pàtàkì nínú ìgbésíayé Kristẹni fún ìbáṣepọ̀ àlààfíà àti èyí tó gbèrú pẹ̀lú Ọlọ́run àti ènìyàn. Kì í ṣe pé Jésù tún ìdáríjìn ṣàlàyé nípa ìgbéayé àti àwọn ẹ̀kọ́ rẹ̀, ṣùgbọ́n ó tún pèsè oore-ọ̀fẹ́ tí a nílò láti gba ìdáríjìn àti láti dárí jin ni nípasẹ̀ Ẹ̀mí rẹ̀. Gbogbo ọmọ Ọlọ́run ni a ti fún ní agbára láti gbọ́ràn sí àṣẹ Ọlọ́run nípa dídáríjin ẹlòmíràn gẹ́gẹ́ bí a ti ṣe dárí jin àwọn tìkalára wọn.