1
KỌRINTI KEJI 11:14-15
Yoruba Bible
Irú rẹ̀ kì í ṣe nǹkan ìjọjú, nítorí Satani pàápàá a máa farahàn bí angẹli ìmọ́lẹ̀. Nítorí náà, kò ṣòro fún àwọn iranṣẹ rẹ̀ láti farahàn bí iranṣẹ tòótọ́. Ṣugbọn ìgbẹ̀yìn wọn yóo rí bí iṣẹ́ wọn.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí KỌRINTI KEJI 11:14-15
2
KỌRINTI KEJI 11:3
Ẹ̀rù ń bà mí pé kí ẹ̀tàn má wọ inú ọkàn yín, tí ẹ óo fi yà kúrò ninu òtítọ́ ati ọkàn kan tí ẹ fi wà ninu Kristi, bí ejò ti fi àrékérekè rẹ̀ tan Efa jẹ.
Ṣàwárí KỌRINTI KEJI 11:3
3
KỌRINTI KEJI 11:30
Bí mo bá níláti fọ́nnu, n óo fọ́nnu nípa àwọn àìlera mi.
Ṣàwárí KỌRINTI KEJI 11:30
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò