1
KỌRINTI KEJI 10:5
Yoruba Bible
ati gbogbo ìdínà tí ó bá gbórí sókè tí ó lòdì sí ìmọ̀ Ọlọrun. A mú gbogbo èrò ọkàn ní ìgbèkùn kí ó lè gbọ́ràn sí Kristi lẹ́nu.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí KỌRINTI KEJI 10:5
2
KỌRINTI KEJI 10:4
nítorí àwọn ohun-ìjà wa kì í ṣe ti ayé, agbára Ọlọrun ni, tí a lè fi wó ìlú olódi. À ń bi gbogbo iyàn jíjà lórí èké ṣubú
Ṣàwárí KỌRINTI KEJI 10:4
3
KỌRINTI KEJI 10:3
Nítorí à ń gbé ìgbé-ayé wa ninu àìlera ti ara, ṣugbọn a kò jagun gẹ́gẹ́ bí ẹni tí ó ń wá ire ara wa
Ṣàwárí KỌRINTI KEJI 10:3
4
KỌRINTI KEJI 10:18
Kì í ṣe ẹni tí ó yin ara rẹ̀ ni ó yege, bíkòṣe ẹni tí Oluwa bá yìn.
Ṣàwárí KỌRINTI KEJI 10:18
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò