1
ÀWỌN ỌBA KEJI 3:17
Yoruba Bible
Ẹ kò ní rí ìjì tabi òjò, sibẹsibẹ àwọn odò gbígbẹ náà yóo kún fún omi, ti yóo fi jẹ́ pé ẹ̀yin ati àwọn mààlúù yín ati àwọn ẹran ọ̀sìn yín yóo rí ọpọlọpọ omi mu.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí ÀWỌN ỌBA KEJI 3:17
2
ÀWỌN ỌBA KEJI 3:15
Ó ní, “Ẹ pe akọrin kan wá.” Bí akọrin náà ti ń kọrin ni agbára OLUWA bà lé Eliṣa
Ṣàwárí ÀWỌN ỌBA KEJI 3:15
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò