1
DIUTARONOMI 23:23
Yoruba Bible
Níwọ̀n ìgbà tí ẹ bá ti fínnúfẹ́dọ̀ jẹ́jẹ̀ẹ́ ohunkohun fún OLUWA Ọlọrun yín, ẹ ti fi ẹnu yín ṣèlérí, ẹ sì níláti rí i pé, ẹ mú ẹ̀jẹ́ náà ṣẹ.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí DIUTARONOMI 23:23
2
DIUTARONOMI 23:21
“Nígbà tí ẹ bá jẹ́ ẹ̀jẹ́ fún OLUWA Ọlọrun yín, ẹ kò gbọdọ̀ má san ẹ̀jẹ́ náà, nítorí OLUWA Ọlọrun yín yóo bèèrè rẹ̀ lọ́wọ́ yín, yóo sì di ẹ̀ṣẹ̀ sí yín lọ́rùn bí ẹ kò bá san án.
Ṣàwárí DIUTARONOMI 23:21
3
DIUTARONOMI 23:22
Ṣugbọn tí ẹ kò bá jẹ́jẹ̀ẹ́ rárá, kì í ṣe ẹ̀ṣẹ̀ fun yín.
Ṣàwárí DIUTARONOMI 23:22
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò