1
DIUTARONOMI 24:16
Yoruba Bible
“Ẹ kò gbọdọ̀ pa baba dípò ọmọ rẹ̀, bẹ́ẹ̀ sì ni ẹ kò gbọdọ̀ pa ọmọ dípò baba, olukuluku ni yóo kú fún ẹ̀ṣẹ̀ tí ó bá dá.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí DIUTARONOMI 24:16
2
DIUTARONOMI 24:5
“Bí ọkunrin kan bá ṣẹ̀ṣẹ̀ gbeyawo, kò gbọdọ̀ jáde lọ sí ojú ogun tabi kí á fún un ní iṣẹ́ ìlú ṣe, ó gbọdọ̀ wà ní òmìnira ninu ilé rẹ̀ fún ọdún kan gbáko, kí ó máa faramọ́ iyawo rẹ̀ tí ó ṣẹ̀ṣẹ̀ fẹ́.
Ṣàwárí DIUTARONOMI 24:5
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò