1
DIUTARONOMI 32:4
Yoruba Bible
“Pípé ni iṣẹ́ ọwọ́ OLUWA, àpáta ààbò yín, gbogbo ọ̀nà rẹ̀ sì jẹ́ ẹ̀tọ́. Olódodo ni Ọlọrun, ẹni tí kì í ṣe àṣìṣe, ẹ̀tọ́ ní í máa ń ṣe nígbà gbogbo.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí DIUTARONOMI 32:4
2
DIUTARONOMI 32:39
“ ‘Ṣé ẹ wá rí i nisinsinyii pé, èmi nìkan ṣoṣo ni Ọlọrun, kò sí ọlọrun mìíràn mọ, lẹ́yìn mi. Mo lè pa eniyan, mo sì lè sọ ọ́ di ààyè. Mo lè ṣá eniyan lọ́gbẹ́, mo sì lè wò ó sàn. Bí mo bá gbá eniyan mú, kò sí ẹni tí ó lè gbà á sílẹ̀ lọ́wọ́ mi.
Ṣàwárí DIUTARONOMI 32:39
3
DIUTARONOMI 32:3
Nítorí pé n óo polongo orúkọ OLUWA, àwọn eniyan rẹ yóo sì sọ nípa títóbi rẹ̀.
Ṣàwárí DIUTARONOMI 32:3
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò