1
DIUTARONOMI 33:27
Yoruba Bible
Ọlọrun ayérayé ni ààbò yín, ọwọ́ rẹ̀ ni ó sì fi ń gbé yín ró. Bí ẹ ti ń súnmọ́ wájú, bẹ́ẹ̀ ni ó ń lé àwọn ọ̀tá yín jáde, tí ó sì ní kí ẹ máa pa wọ́n run.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí DIUTARONOMI 33:27
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò