1
DIUTARONOMI 34:10
Yoruba Bible
Láti ìgbà náà, kò tíì sí wolii mìíràn ní ilẹ̀ Israẹli tí ó dàbí Mose, ẹni tí Ọlọrun bá sọ̀rọ̀ lojukooju.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí DIUTARONOMI 34:10
2
DIUTARONOMI 34:9
Joṣua ọmọ Nuni kún fún ọgbọ́n nítorí pé Mose ti gbé ọwọ́ rẹ̀ lé e, nítorí náà àwọn ọmọ Israẹli ń gbọ́ tirẹ̀, wọ́n sì ń ṣe gẹ́gẹ́ bí àṣẹ tí OLUWA pa fún Mose.
Ṣàwárí DIUTARONOMI 34:9
3
DIUTARONOMI 34:7
Mose jẹ́ ẹni ọgọfa (120) ọdún nígbà tí ó kú, ojú rẹ̀ kò ṣe bàìbàì, bẹ́ẹ̀ ni agbára rẹ̀ kò dínkù.
Ṣàwárí DIUTARONOMI 34:7
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò