1
ÌWÉ ONÍWÀÁSÙ 7:9
Yoruba Bible
Má máa yára bínú, nítorí àyà òmùgọ̀ ni ibinu dì sí.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí ÌWÉ ONÍWÀÁSÙ 7:9
2
ÌWÉ ONÍWÀÁSÙ 7:14
Máa yọ̀ nígbà tí ó bá dára fún ọ, ṣugbọn nígbà tí nǹkan kò bá dára, máa ranti pé Ọlọrun ló ṣe mejeeji. Nítorí náà, eniyan kò lè mọ ohun tí ń bọ̀ wá ṣẹlẹ̀ lẹ́yìn ọ̀la.
Ṣàwárí ÌWÉ ONÍWÀÁSÙ 7:14
3
ÌWÉ ONÍWÀÁSÙ 7:8
Òpin nǹkan sàn ju ìbẹ̀rẹ̀ rẹ̀ lọ, sùúrù sì dára ju ìwà ìgbéraga lọ.
Ṣàwárí ÌWÉ ONÍWÀÁSÙ 7:8
4
ÌWÉ ONÍWÀÁSÙ 7:20
Kò sí olódodo kan láyé tí ń ṣe rere, tí kò lẹ́ṣẹ̀.
Ṣàwárí ÌWÉ ONÍWÀÁSÙ 7:20
5
ÌWÉ ONÍWÀÁSÙ 7:12
Nítorí pé bí ọgbọ́n ṣe jẹ́ ààbò, bẹ́ẹ̀ ni owó náà jẹ́ ààbò; anfaani ìmọ̀ ni pé, ọgbọ́n a máa dáàbò bo ọlọ́gbọ́n.
Ṣàwárí ÌWÉ ONÍWÀÁSÙ 7:12
6
ÌWÉ ONÍWÀÁSÙ 7:1
Orúkọ rere dára ju òróró olówó iyebíye lọ, ọjọ́ ikú sì dára ju ọjọ́ ìbí lọ.
Ṣàwárí ÌWÉ ONÍWÀÁSÙ 7:1
7
ÌWÉ ONÍWÀÁSÙ 7:5
Ó dára kí eniyan fetí sí ìbáwí ọlọ́gbọ́n, ju láti máa gbọ́ orin ìyìn àwọn òmùgọ̀ lọ.
Ṣàwárí ÌWÉ ONÍWÀÁSÙ 7:5
8
ÌWÉ ONÍWÀÁSÙ 7:2
Ó dára láti lọ sí ilé àwọn tí ń ṣọ̀fọ̀ ju ati lọ sí ibi àsè lọ, nítorí pé àwọn alààyè gbọdọ̀ máa rán ara wọn létí pé ikú ni òpin gbogbo eniyan. Gbogbo alààyè ni wọ́n gbọdọ̀ máa fi èyí sọ́kàn.
Ṣàwárí ÌWÉ ONÍWÀÁSÙ 7:2
9
ÌWÉ ONÍWÀÁSÙ 7:4
Ọkàn ọlọ́gbọ́n wà ní ilé àwọn tí ń ṣọ̀fọ̀, ṣugbọn ọkàn òmùgọ̀ wà ní ibi ìgbádùn.
Ṣàwárí ÌWÉ ONÍWÀÁSÙ 7:4
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò