ÌWÉ ONÍWÀÁSÙ 7:5

ÌWÉ ONÍWÀÁSÙ 7:5 YCE

Ó dára kí eniyan fetí sí ìbáwí ọlọ́gbọ́n, ju láti máa gbọ́ orin ìyìn àwọn òmùgọ̀ lọ.