1
AISAYA 12:2
Yoruba Bible
Wò ó! Ọlọrun ni olùgbàlà mi, n óo gbẹ́kẹ̀lé e ẹ̀rù kò sì ní bà mí, nítorí pé OLUWA Ọlọrun ni agbára mi, ati orin mi, òun sì ni Olùgbàlà mi.”
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí AISAYA 12:2
2
AISAYA 12:3
Tayọ̀tayọ̀ ni ẹ óo fi máa rí ìgbàlà bí ẹni pọn omi láti inú kànga.
Ṣàwárí AISAYA 12:3
3
AISAYA 12:5
Ẹ kọ orin ìyìn sí OLUWA nítorí ó ṣe nǹkan tí ó lógo, jẹ́ kí èyí di mímọ̀ ní gbogbo ayé.
Ṣàwárí AISAYA 12:5
4
AISAYA 12:4
Ẹ óo sọ ní ọjọ́ náà pé, “Ẹ fọpẹ́ fún OLUWA, ẹ ké pe orúkọ rẹ̀, ẹ kéde iṣẹ́ rere rẹ̀ láàrin àwọn orílẹ̀-èdè; ẹ kéde pé a gbé orúkọ rẹ̀ ga.
Ṣàwárí AISAYA 12:4
5
AISAYA 12:1
O óo sọ ní ọjọ́ náà pé, “N óo fi ọpẹ́ fún OLUWA, nítorí pé bí ó tilẹ̀ bínú sí mi, inú rẹ̀ ti rọ̀, ó sì tù mí ninu.
Ṣàwárí AISAYA 12:1
6
AISAYA 12:6
Ẹ̀yin tí ń gbé Sioni, ẹ hó, ẹ kọrin ayọ̀, ẹ̀yin olùgbé Sioni, nítorí Ẹni ńlá ni Ẹni Mímọ́ Israẹli tí ó wà láàrin yín.”
Ṣàwárí AISAYA 12:6
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò