1
AISAYA 17:1
Yoruba Bible
Ọ̀rọ̀ OLUWA sí ilẹ̀ Damasku nìyí: “Damasku kò ní jẹ́ ìlú mọ́ òkítì àlàpà ni yóo dà.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí AISAYA 17:1
2
AISAYA 17:3
Ìlú olódi kò ní sí mọ́ ní Efuraimu, kò sì ní sí ìjọba mọ́ ní Damasku, àwọn tí wọ́n bá ṣẹ́kù ní Siria yóo sì dàbí ògo àwọn ọmọ Israẹli, OLUWA àwọn ọmọ ogun ló sọ bẹ́ẹ̀.
Ṣàwárí AISAYA 17:3
3
AISAYA 17:4
“Tó bá di ìgbà náà, a óo rẹ ògo àwọn ọmọ Israẹli sílẹ̀, ọrọ̀ wọn yóo di àìní.
Ṣàwárí AISAYA 17:4
4
AISAYA 17:2
Àwọn ìlú rẹ̀ yóo di àkọ̀tì títí lae wọn yóo di ibùjẹ àwọn ẹran, níbi tí àwọn ẹran yóo dùbúlẹ̀, tí ẹnikẹ́ni kò sì ní dẹ́rùbà wọ́n.
Ṣàwárí AISAYA 17:2
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò