1
AISAYA 26:3
Yoruba Bible
O óo pa àwọn tí wọ́n gbé ọkàn wọn lé ọ mọ́ ní alaafia pípé, nítorí pé wọ́n gbẹ́kẹ̀lé ọ.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí AISAYA 26:3
2
AISAYA 26:4
Gbẹ́kẹ̀lé OLUWA títí lae, nítorí àpáta ayérayé ni OLUWA Ọlọrun.
Ṣàwárí AISAYA 26:4
3
AISAYA 26:9
Ọkàn mi ń ṣe àfẹ́rí rẹ lálẹ́, mo sì ń fi tọkàntọkàn wá ọ nítorí nígbà tí ìlànà rẹ bá wà láyé ni àwọn ọmọ aráyé yóo kọ́ òdodo.
Ṣàwárí AISAYA 26:9
4
AISAYA 26:12
OLUWA ìwọ yóo fún wa ní alaafia, nítorí pé ìwọ ni o ṣe gbogbo iṣẹ́ wa fún wa.
Ṣàwárí AISAYA 26:12
5
AISAYA 26:8
Àwa dúró dè ọ́ ní ọ̀nà ìdájọ́ rẹ, OLUWA, orúkọ rẹ ati ìrántí rẹ ni ọkàn wa ń fẹ́.
Ṣàwárí AISAYA 26:8
6
AISAYA 26:7
Ọ̀nà títẹ́jú ni ọ̀nà àwọn olódodo ó mú kí ọ̀nà àwọn olódodo máa dán.
Ṣàwárí AISAYA 26:7
7
AISAYA 26:5
Ó sọ àwọn tí ń gbé orí òkè kalẹ̀, ó sọ ìlú tí ó wà ní orí òkè téńté di ilẹ̀, ó sọ ọ́ di ilẹ̀ patapata, ó fà á sọ sinu eruku.
Ṣàwárí AISAYA 26:5
8
AISAYA 26:2
Ẹ ṣí ìlẹ̀kùn ibodè, kí orílẹ̀-èdè olódodo, tí ń ṣe òtítọ́ lè wọlé.
Ṣàwárí AISAYA 26:2
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò