1
AISAYA 32:17
Yoruba Bible
Àyọrísí òdodo yóo sì jẹ́ alaafia, ìgbẹ̀yìn rẹ̀ yóo sì jẹ́ ìbàlẹ̀ àyà wa, ati igbẹkẹle OLUWA títí lae.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí AISAYA 32:17
2
AISAYA 32:18
Àwọn eniyan mi yóo máa gbé pẹlu alaafia, ní ibùgbé tí ó ní ààbò ati ibi ìsinmi tí ó ní ìbàlẹ̀ àyà.
Ṣàwárí AISAYA 32:18
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò