1
NỌMBA 12:8
Yoruba Bible
Lojukooju ni èmi í máa bá a sọ̀rọ̀; ọ̀rọ̀ ketekete sì ni, kì í ṣe àdììtú ọ̀rọ̀. Kódà, òun a máa rí ìrísí OLUWA. Kí ló dé tí ẹ kò fi bẹ̀rù ati sọ̀rọ̀ òdì sí i?”
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí NỌMBA 12:8
2
NỌMBA 12:3
Mose ni ó jẹ́ oníwà ìrẹ̀lẹ̀ jù ninu gbogbo ẹni tí ó wà láyé.
Ṣàwárí NỌMBA 12:3
3
NỌMBA 12:6
OLUWA sì sọ fún wọn pé, “Ẹ gbọ́ ohun tí n óo sọ yìí: Nígbà tí àwọn wolii wà láàrin yín, èmi a máa fi ara hàn wọ́n ninu ìran, èmi a sì máa bá wọn sọ̀rọ̀ lójú àlá.
Ṣàwárí NỌMBA 12:6
4
NỌMBA 12:7
Ṣugbọn ti Mose, iranṣẹ mi yàtọ̀. Mo ti fi ṣe alákòóso àwọn eniyan mi.
Ṣàwárí NỌMBA 12:7
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò