1
ORIN DAFIDI 119:105
Yoruba Bible
Ọ̀rọ̀ rẹ ni àtùpà fún ẹsẹ̀ mi, òun ni ìmọ́lẹ̀ sí ọ̀nà mi.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí ORIN DAFIDI 119:105
2
ORIN DAFIDI 119:11
Mo ti fi ọ̀rọ̀ rẹ sọ́kàn, kí n má baà ṣẹ̀ ọ́.
Ṣàwárí ORIN DAFIDI 119:11
3
ORIN DAFIDI 119:9
Báwo ni ọdọmọkunrin ṣe lè mú kí ọ̀nà rẹ̀ mọ́? Nípa títẹ̀lé ọ̀rọ̀ rẹ ni.
Ṣàwárí ORIN DAFIDI 119:9
4
ORIN DAFIDI 119:2
Ayọ̀ ń bẹ fún àwọn tí ń pa òfin rẹ̀ mọ́, tí wọn ń fi tọkàntọkàn ṣe ìfẹ́ rẹ̀.
Ṣàwárí ORIN DAFIDI 119:2
5
ORIN DAFIDI 119:114
Ìwọ ni ibi ìpamọ́ mi ati asà mi, mo ní ìrètí ninu ọ̀rọ̀ rẹ.
Ṣàwárí ORIN DAFIDI 119:114
6
ORIN DAFIDI 119:34
Là mí lóye, kí n lè máa pa òfin rẹ mọ́, kí n sì máa fi tọkàntọkàn pa wọ́n mọ́.
Ṣàwárí ORIN DAFIDI 119:34
7
ORIN DAFIDI 119:36
Mú kí ọkàn mi fà sí òfin rẹ, kí ó má fà sí ọrọ̀ ayé.
Ṣàwárí ORIN DAFIDI 119:36
8
ORIN DAFIDI 119:71
Ìpọ́njú tí mo rí ṣe mí ní anfaani, ó mú kí n kọ́ nípa ìlànà rẹ.
Ṣàwárí ORIN DAFIDI 119:71
9
ORIN DAFIDI 119:50
Ohun tí ó ń tù mí ninu ní àkókò ìpọ́njú ni pé: ìlérí rẹ mú mi wà láàyè.
Ṣàwárí ORIN DAFIDI 119:50
10
ORIN DAFIDI 119:35
Tọ́ mi sí ọ̀nà nípa òfin rẹ, nítorí pé mo láyọ̀ ninu rẹ̀.
Ṣàwárí ORIN DAFIDI 119:35
11
ORIN DAFIDI 119:33
OLUWA, kọ́ mi ní ìlànà rẹ, n óo sì pa wọ́n mọ́ dé òpin.
Ṣàwárí ORIN DAFIDI 119:33
12
ORIN DAFIDI 119:28
Ìrẹ̀wẹ̀sì bá ọkàn mi nítorí ìbànújẹ́, mú mi lọ́kàn le gẹ́gẹ́ bí ọ̀rọ̀ rẹ.
Ṣàwárí ORIN DAFIDI 119:28
13
ORIN DAFIDI 119:97
Mo fẹ́ràn òfin rẹ lọpọlọpọ! Òun ni mo fi ń ṣe àṣàrò tọ̀sán-tòru.
Ṣàwárí ORIN DAFIDI 119:97
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò