1
ORIN DAFIDI 43:5
Yoruba Bible
Ìwọ ọkàn mi, kí ló dé tí o fi rẹ̀wẹ̀sì? Kí ló dé tí ara rẹ kò fi balẹ̀ ninu mi? Gbẹ́kẹ̀ rẹ lé Ọlọrun; nítorí pé n óo tún yìn ín, olùrànlọ́wọ́ mi ati Ọlọrun mi.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí ORIN DAFIDI 43:5
2
ORIN DAFIDI 43:3
Rán ìmọ́lẹ̀ rẹ ati òtítọ́ rẹ jáde, jẹ́ kí wọ́n máa tọ́ mi sọ́nà; jẹ́ kí wọ́n mú mi wá sí orí òkè mímọ́ rẹ, ati ibùgbé rẹ.
Ṣàwárí ORIN DAFIDI 43:3
3
ORIN DAFIDI 43:1
Dá mi láre, Ọlọrun, kí o sì gbèjà mi, lọ́dọ̀ àwọn tí kò mọ̀ Ọ́; gbà mí lọ́wọ́ àwọn ẹlẹ́tàn ati alaiṣootọ.
Ṣàwárí ORIN DAFIDI 43:1
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò