1
ORIN DAFIDI 91:2
Yoruba Bible
yóo wí fún OLUWA pé, “Ìwọ ni ààbò ati odi mi, Ọlọrun mi, ẹni tí mo gbẹ́kẹ̀lé.”
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí ORIN DAFIDI 91:2
2
ORIN DAFIDI 91:1
Ẹni tí ń gbé abẹ́ ààbò Ọ̀gá Ògo, tí ó wà lábẹ́ òjìji Olodumare
Ṣàwárí ORIN DAFIDI 91:1
3
ORIN DAFIDI 91:15
Yóo pè mí, n óo sì dá a lóhùn; n óo wà pẹlu rẹ̀ ninu ìṣòro, n óo yọ ọ́ ninu rẹ̀, n óo dá a lọ́lá.
Ṣàwárí ORIN DAFIDI 91:15
4
ORIN DAFIDI 91:11
Nítorí yóo pàṣẹ fún àwọn angẹli rẹ̀, nítorí rẹ, pé kí wọ́n máa pa ọ́ mọ́ ní gbogbo ọ̀nà rẹ.
Ṣàwárí ORIN DAFIDI 91:11
5
ORIN DAFIDI 91:4
Yóo da ìyẹ́ rẹ̀ bò ọ́, lábẹ́ ìyẹ́ apá rẹ̀ ni o óo ti rí ààbò; òtítọ́ rẹ̀ ni yóo jẹ́ asà ati apata rẹ.
Ṣàwárí ORIN DAFIDI 91:4
6
ORIN DAFIDI 91:9-10
Nítorí tí ìwọ ti fi OLUWA ṣe ààbò rẹ, o sì ti fi Ọ̀gá Ògo ṣe ibùgbé rẹ, ibi kankan kò ní dé bá ọ, bẹ́ẹ̀ ni àjálù kankan kò ní súnmọ́ ilé rẹ.
Ṣàwárí ORIN DAFIDI 91:9-10
7
ORIN DAFIDI 91:3
Nítorí yóo yọ ọ́ ninu okùn àwọn pẹyẹpẹyẹ ati ninu àjàkálẹ̀ àrùn apanirun.
Ṣàwárí ORIN DAFIDI 91:3
8
ORIN DAFIDI 91:7
Ẹgbẹrun lè ṣubú ní ẹ̀gbẹ́ rẹ, tabi ẹgbaarun ni apá ọ̀tún rẹ; ṣugbọn kò ní súnmọ́ ọ̀dọ̀ rẹ.
Ṣàwárí ORIN DAFIDI 91:7
9
ORIN DAFIDI 91:5-6
O ò ní bẹ̀rù ìdágìrì òru, tabi ọfà tí ń fò kiri ní ọ̀sán, tabi àjàkálẹ̀ àrùn tí ń jà kiri ninu òkùnkùn, tabi ìparun tí ń ṣeni lófò ní ọ̀sán gangan.
Ṣàwárí ORIN DAFIDI 91:5-6
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò